Págà! A kò rí oun tó jọ "Morọ́lá"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Morọ́lákẹ́
Meaning: I have found wealth/nobility to cherish.
Morọ́lábí
Meaning: I have found wealth to birth.
Morọ́lápé
Meaning: I have wealth to be complete.
Morọ́láyọ̀
Meaning: I've found nobility, and I'm glad.
Morọ́lágbé
Meaning: I've found wealth to carry.
Morọ́ládé
Meaning: I've found wealth return.
Morọ́láolúwa
Meaning: I have seen the blessing (or goodness, or benefit or majesty) of the Lord.
Morọ́láolúwakẹ́
Meaning: I found the blessing of God (this child) to cherish.
Morọ́láún
Meaning: I've found wealth (in this child) to pamper.