Págà! A kò rí oun tó jọ "Kọ̀ya"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adékọyà
Meaning: The crown rejects suffering (on our behalf). Royalty defended us (from suffering).
Ọkọ́ya
Meaning: The hoe broke.
Onàkọyà
Meaning: Ornaments have rejected suffering.
Ọṣìkọ̀yà
Meaning: The king (who) defends his subjects from suffering.
Fákọ̀yà
Meaning: Ifá rejected suffering.
Ọrẹ̀kọ̀yà
Meaning: The Ọrẹ̀ deity rejected (our) suffering.
Ẹfúnkọ̀yà
Meaning: Purity fought suffering (for me).
Odùkọ̀yà
Meaning: Odu (ifa) rejected suffering (on my behalf).
Ṣókọ̀yà
Meaning: The sorcerer rejected suffering (for me).
Mofikọ̀yà
Meaning: I reject suffering with this.
Shókọ̀yà
Meaning: The fertility god rejected suffering.
Ọbákọ̀yà
Meaning: The king rejected suffering. Ọbalúayé rejected suffering.
Àgbẹ́kọ̀yà
Meaning: Farmer resists suffering.
Ọlọ́runkọ̀yà
Meaning: God rejected suffering.
Ọ̀rúnkọ̀yà
Meaning: Heaven rejects suffering (on our behalf).
Adémókoyá
Meaning: Royalty helps improve (our) culture of farming.
Ọkọ́ṣẹ́
Meaning: The hoe broke.