Págà! A kò rí oun tó jọ "Gbádé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Gbádégeṣin
Meaning: Put the crown on the horse.
Gbádéyanká
Meaning: (One who) struts with the crown.
Gbádébọ̀
Meaning: Returns with the crown.
Gbadéwọlé
Meaning: Receive a crown with which to enter.
Gbádéyanjú
Meaning: Carry the crown completely.
Gbádégẹshin
Meaning: Put royalty on a horse.
Gbádéyan
Meaning: (One who) struts with the crown.
Gbádéwùnwọ́n
Meaning: (We) make them envious of the (our) crown.
Gbádérìnká
Meaning: Walk around with a crown.
Gbádérìn
Meaning: Walks with the crown.
Gbádérìnwá
Meaning: Brings a crown with him/her.