Págà! A kò rí oun tó jọ "Dúpẹ́"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Modúpẹ́
Meaning: I am thankful.
Modúpẹ́ọlá
Meaning: I am thankful for wealth.
Modúpẹ́olúwa
Meaning: I am thankful, Lord.
Modúpẹ́adé
Meaning: I am thankful for the crown.
Modúpẹ́oyè
Meaning: I am thankful for chieftaincy (honour).
Modúpẹ́oreolúwa
Meaning: I'm thankful for God's goodness.
Fèyídúpẹ́
Meaning: Be thankful with this (child).
Ifámodúpẹ́
Meaning: Ifá, I'm grateful.
Olúwamodúpẹ́
Meaning: I thank you, God.