Págà! A kò rí oun tó jọ "Dínà"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Ọdẹ́dínà
Meaning: The hunter blocked the way.
Ọ̀súndínà
Meaning: Ọ̀sun blocked the way.
Egúndínà
Meaning: Masquerade blocked the path.
Ẹkúndínà
Meaning: Tears blocked the way.
Echudina
Meaning: In Cuban usage, the belief is that it means "Echu of the flame/fire." In Yorùbá language, "Ès̩údínà" means "Èṣú blocks the road (from enemies)."
Ọbádínà
Meaning: 1. The king blocked the road (against our enemies). 2. Obaluaye blocked the road (against our enemies).
Omídínà
Meaning: Water blocked the (bad) path.
Okàntómi
Meaning: This is a name given after ordination of an Orisha priest/ess in the Afro-Cuban Yoruba religious tradition known as Lukumi/Santeria/Regla de Ocha. This particular name is given to Oshun worshipers, and believed to mean something like "Oshun's Heart" "Heart of Water" "Heart that is water" or even "Oshun is sufficient".
Ìyanu
Meaning: Surprise. Miracle