Págà! A kò rí oun tó jọ "Dalẹ́"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adálémọ
Meaning: One who build by himself without external assistance.
Bọ́ládalẹ́
Meaning: Go with nobility until till the end.
Aróhundálejòdúró
Meaning: He who has something to refresh visitors thus making them stay longer.
Mobọ́ládalẹ́
Meaning: I've taken wealth/luxury into my old age. [See below for extra information about the name.]
Yẹmídalẹ́
Meaning: May I remain graceful until old age.