Págà! A kò rí oun tó jọ "Wádé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Síjúwadé
Meaning: Glimpses royalty.
Dúrówadé
Meaning: Wait to see the crown.
Olúwadé
Meaning: The lord is present.
Ọ̀páwádé
Meaning: The one the Ọ̀pá deity sought here.
Bólúwadé
Meaning: One who came with the lord.
Olúkówadé
Meaning: Prominence entered royalty.
Olúwadémiládé
Meaning: God has crowned me.
Olúwadéàdúràmiládé
Meaning: God has crowned my prayers.
Ẹlẹ́wàdé
Meaning: The beautiful one has come.
Olúwádémiládéògo
Meaning: Lord, cover me with a crown of glory.
Iyìolúwadémiládé
Meaning: The honour of God has crowned me (with the birth of my son).
Tẹ́níwadé
Meaning: Welcome royalty with pomp.
Bẹ́wàdé
Meaning: Arrived with beauty.
Adéwùsì
Meaning: Royalty multiplies/is influential.
Démiládé
Meaning: Crown me. Put a crown on my head.
Ṣíjúwọlá
Meaning: (I) opened my eyes to wealth.